AduBible.org® Parallel Scripture Sanctuary • 100% Ads-Free

Jẹ́nẹ́sísì Orí 1 (BMYO 2021) — Ìbẹ̀rẹ̀ Dídá Ayé & Spoken Audio

Ní ìbẹ̀rẹ̀ ohun gbogbo Ọlọ́run dá àwọn ọ̀run àti ayé. Ayé sì wà ní rúdurùdu, ó sì ṣófo, òkùnkùn sì wà lójú ibú omi, Ẹ̀mí Ọlọ́run sì ń rábàbà lójú omi. Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà,” ìmọ́lẹ̀ sì wà.

Scripture Text Preview — Jẹ́nẹ́sísì Orí 1 (BMYO 2021) — Ìbẹ̀rẹ̀ Dídá Ayé & Spoken Audio

1. Ní ìbẹ̀rẹ̀ ohun gbogbo Ọlọ́run dá àwọn ọ̀run àti ayé.

2. Ayé sì wà ní rúdurùdu, ó sì ṣófo, òkùnkùn sì wà lójú ibú omi, Ẹ̀mí Ọlọ́run sì ń rábàbà lójú omi.

3. Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà,” ìmọ́lẹ̀ sì wà.

4. Ọlọ́run rí i pé ìmọ́lẹ̀ náà dára, ó sì ya ìmọ́lẹ̀ náà kúrò lára òkùnkùn.

5. Ọlọ́run sì pe ìmọ́lẹ̀ ní “ọ̀sán,” òkùnkùn sì ni ó pe ní “òru.” Ìrọ̀lẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.

Exegetical & Lexical Notes: Matches Biblica® Bíbélì Mímọ́ ti Òde Òní (BMYO / 911) and Davar Partners spoken audio 100% word-for-word.

Parallel Bible Study, Strong’s Concordance, 24kHz Audio & Offline Vault

Compare this passage side-by-side in up to 4 synchronized columns across NKJV, KJV, BSB, Original Hebrew (WLC), Koine Greek (Textus Receptus), Asante Twi (Twerɛ Kronkron), French, Spanish, German, and 35+ global languages on AduBible.org®. Tap any verse for Strong’s Exhaustive Concordance numbers, Matthew Henry & John Gill commentaries, 24kHz Neural Audio streaming, and 100% offline PWA access.